Courts résumés des chapitres en Yoruba (LÁKÒÓTÁN)
1. Famille, Activités et Besoins socioéconomiques
SOSSA Bruno, ATCHA Isséré et AMADOU SANNI Moutaou
Gẹ́gẹ́bíòuntí a ríkà, 44343 ni gbogboàwọnènìyàntí ń bẹníìlú Tchaourou, títóunṣeọdọ, bẹ́ẹ̀ pẹ̀lúàwọnobìnrintóunpọ̀ jùàwọnọkùnrinlọ. Ẹ̀kọ́, iṣẹ́ àti ara yíyafúnọmọbíbíjẹ́ àwọnohunàìníwónnípaowó, eléyìílófààwọnèsowọnyìí.
NAHINI Tchando Ambroise
ÀwọnèdèYorùbáàtiShabẹ́, àwọnèdèbariba, àwọnèdèfọnàtiàwọnèdèmíràntódapomọèyítí a mẹ́nubáyìíníàwọnèdètí ó pòjùlọníilẹ̀ Tchaourou.
AÏSSOUN Florette et AGBO Maxime
Ìwéyìító ń fẹ́ púpọ̀ latisọ̀rọ̀ lóríàwọnipaoroamuyelóríàìníohunìníìgbésíayéníilẹ̀ Tchaourou. Ó fíhànpéàwọntóyẹfúnọ̀gáìdílélátiṣe (ìbálòpọ̀, iyeàwọnènìyànìdílénáà, àwọnmélòóníwón ń kàwé, ṣeẹniyìíníìyàwótàbíkóní, irúiṣẹ́ wóló ń ṣe). Gbogboàwọnohuntí á kàbáyìíníwónlọ́wọ́ nínúàìníohunìníìgbésíayéníìlú Tchaourou.
GBADAMASSI Alassane
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọnọmọdéàtiọdọtíwọ́nfíilé-ìwésílẹ̀ níìlú Tchaourou, níwónfíilé-ìwésílẹ̀ níilé-ẹ̀kọ́ kejì. Iṣẹ́ aṣọkikoàtiirundídìníṣeiṣẹ́ pàtàkìtíwọnlọ́wọ́ látikọ́, bẹ́ẹ̀ pẹluòwòṣíṣetóunjẹ́ iṣẹ́ owófúnwón.
2. Scolarisation
HOUESSIGBEDE Anselme et ALLADATIN Judicaël
Lóríẹgbẹ̀rúnọmọníilé-ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́, bíméjìdínlógúnníwónṣubúníilé-ìwéníọdún 2014-2015. Ọrọnípaìgbéayéàwọnòbítàbíìdílépẹ̀lúìṣe ara ẹni ni wónjẹ́ àwọnìdítí a lè tenu mọláti fi ìtumọ̀ síàwọnìṣeyìí.
ADJE Elihou et AMADOU SANNI Mouftaou
Iṣewáń fi hànwápé, lóríọmọmẹtatíókúròníilé-ìwéníìlú Tchaourou, méjìnínúwọnjẹ́ àwọntíó kúròláìparíilé-ìwémẹ́fàtíilé-ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ tíńṣeCM2.
FERNANDO Judicaël
Lóríàwọnọmọdéàtiọdọmẹ́wàátí ó fi ilé-ìwésílẹ̀, méjeláàrin won lójẹ́ obìnrin. Bẹ́ẹ̀ gẹgẹ ni, àbọ̀ nínúwọn ni kòníìtọ́nilọ́nàgidigbàkí ó tó fi ilé-ìwésílẹ̀.
KINTOMONHO Bill-Lucas
Ìlọsíwájúàwọntíwọn ń ṣiṣẹnílé-ìwé ni ọwọìfàsẹyìnlátiọ̀dọ̀ àwọnìdíléńlá, àwọnòbítíwón ń kàwéàtiibẹayétálákààwọnòbínínúìlú Tchaourou.
3. Santé de la Reproduction des Adolescents et Jeunes (SRAJ)
LARE Landrine et AMADOU SANNI Mouftaou
Nínúagbegbeàárínìlú Tchaourou, oyounàkọ́kọ́ lọdọàwọnọmọdéobinrinmáa ń berelatiọdúnmanrundínlógúnbẹ́ẹ̀ sìníìdító ń ṣàkósoníàlèkábáyìí : wíwònínúidapọ̀ ìfẹ́, fífiilé-ìwésílẹ̀, í pàdánùìfẹ́ àtiidapọ̀ àwoòbíàtiàníyàn ara líle.
EZIN Robert
Nínúìlú Tchaourou, díẹ̀ láàárínàwọnọmọdéàtiọdọní won ròpé, ìfẹ́ látitẹsíwájúnínúilé-ìwé, àníyànjiyànàwọnòbí, àìníowólọ́wọ́ fúnitọjuoyún na ló ń fàoyúnṣíṣẹ́. Síbẹ̀, púpọ̀ àwọnẹlòmíràn ń ròpéobìnrin ó gbọ́dọ̀ ṣẹ́gunoyunnítoríàwọnọ̀rọ̀ ìbáwíàwọnìsìnàtiàwọnohuntíoyúnṣíṣẹ́ lèfà.
TOYI Macaire
Isẹyìí fi hànwápélóríọmọdéàtiọdọtí a fi síilé-ìwéníìlú Tchaourou, mẹtanínúwón ti mọnípaifẹìbálòpọ̀ tọkọtabo; bí ó ṣerílọdọàwọnobìnrinbẹ́ẹ̀ gẹgẹní ó ṣerílọdọàwọnọkùnrinnáà.
BARANON Djima et AMADOU SANNI Mouftaou
Lóríẹgbẹ̀rúobìnrin, mẹ́jọpéréló ń ṣeètòọmọbibigẹ́gẹ́bí « planning familial » nínúàárínìlú Tchaourou.
SALIFOU Mohamadou et ALLADATIN Judicaël
Ìbálòpọ̀ láìtóàsìkò a gbọ́ kan ìgbéyàwóláìtásìkòpẹluàìmálòàwọnètòọmọbibi(planning familial), gbogbonǹkanwọ̀nyífúnwàníìtumòlóríọmọ bibi láìtásìkòlọdọọmọdéobìnrinníìlú Tchaourou.
GBAGUIDI Timar
Nínúisẹyìí, a fíhànpé, nínúọdunkọ̀ọ̀kan, iyeàwọnọmọọdọobìnrintómáa ń lóyún, máa ń gòkèsíínínúilé-ìwé Tchaourou. Àwọnoyúnyìímáa ń wáyéláàárínọdúnmarundínlógúnàtimẹtadínlógúnbẹ́ẹ̀ sìníméjeláàárínàwọnọmọilé-ìwélórímẹwamáa ń fi ilé-ìwésílẹ̀ nígbàtíwóntílóyúntán.